Bibeli wipe “Sugbon a sa a li ogbe nitori irekoja wa, a pa a li ara nitori aisedede wa; ina alafia wa wa lara Re,
ati nipa ina Re li a fi mu wa lara da.” Isa. 53:5
Mo so pelu igbagbo wipe “Ilera pipe ni ti emi ati Ile mi ni ojo gbogbo nitori ti a ti wo mi san nipa ina Re.