Bibeli wipe “ Nitorinaa mo fi iyonu Olorun be yin, ara, ki eyin fi ara yin fun Olorun ni ebo aaye, Mimo, itewogba, eyi ni ise isin yin ti o tona”

    Mo so pelu igbagbo wipe “Ninu odun yi ati ni ojo aye mi gbogbo, emi o sin Kristi tokantokan. Ire ati Ibukun awon Olufokansin toto yo je temi ni iha gbogbo ni Oruko Jesu Kristi. Amin.  Romu 12:1

Leave a Reply