Bibeli wipe “Nitori Olorun feran araye to bee ge, ti o fi Omo bibi Re kansoso funni, ki enikeni ti o ba gba a gbo ma ba segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun”
John 3:16
‘Nitori ti mo ti gba Jesu ti se ebun Olorun fun igbala araye,
Mo so pelu Igbagbo wipe “Ore-Ofe ati Ibukun gbogbo ti o ti ipase re wa, ko ni fo mi ru” ni Oruko Jesu Kristi. Amin.