Bibeli wipe “Bi eyin ba fe ti e si gboran, Eyin o je ire ile naa.”
Isaiah 1:19
Mo so pelu Igbagbo wipe “Oluwa yio fun mi ni eti igbo ati aya igbase lati se ife Re. Nipa be emi yio ri oju rere gba beni un o si di alabukun fun ni Oruko Jesu Kristi Oluwa wa. Amin.