Bibeli wipe “Nitori naa awa ni iko fun Kristi, bi eni pe Olorun n ti odo wa sipe fun yin;

awa nbe yin nipo Kristi, e ba Olorun laja.” II Cor. 5:20

 

Mo so pelu Igbagbo wipe “Oun ti ma nde ba enia ti ki le je iko fun Kristi mo ti si ma so eni di ota Olorun

ko ni de ba mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

 

Leave a Reply