Bibeli wipe “Oro re ni fitila si ese mi ati imole si ipa ona mi.”

Ps. 119:105.

 

Mo so pelu Igbagbo wipe “Olorun yio tan imole si okunkun aye mi nipa oro Re,

okunkun aye ko ni bo emi ati ebi mi mo le.  Ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

 

Leave a Reply