Bibeli wipe “Ibukun ni fun eniti o ni Olorun Jakobu fun iranlowo re, ireti eniti mbe lodo Oluwa Olorun re”. Ps. 146:5

 

    Mo so pelu Igbagbo wipe “Niwon igbati mo ti gbekele Olorun fun iranlowo, Yio bukun fun Emi ati Ebi mi,

Yio si mu inu wa dun ni ojo aye wa, ni Oruko Jesu Kristi.   Amin.

 

Leave a Reply