Bibeli wipe “Ninu ododo ni a o fi idi re mule; Iwo o jinna si inira; nitori iwo ki yoo beru; ati siifoya, nitori ki yoo sunmo o”. Isa. 54:14
Mo so pelu Igbagbo wipe “Olorun yio fi idi ise rere re mule ninu mi, Emi ati Ebi mi yio jinna si inira, A o si ma gbe ni alafia pipe, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.