Bibeli wipe “Oorun ki yio pa o nigba osan, tabi osupa nigba oru. Oluwa yio pa o mo kuro ninu ibi gbogbo, yio pa okan re mo”.
Ps. 121:6-7
Mo so pelu Igbagbo wipe “Olorun Yio pa emi ati ebi mi mo kuro ninu ibi gbogbo beni aabo Re Yio si daju lori wa, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.