Bibeli wipe “Oju ohun gbogbo nwo O; Iwo si fun won li ounje won li akoko re”.

Psalm 145:15

 

 

Mo so pelu Igbagbo wipe “Emi yio duro de Oluwa ni ojo aye mi gbogbo.

Oun yio si pese ni kikun fun aini mi ati Ebi mi. Ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

 

Leave a Reply