Bibeli wipe “Ki Olorun ki o saanu fun wa, ki o si busi fun wa; Ki o si se oju Re ki o mole si wa lara”.
Psalm 67:1
Mo so pelu Igbagbo wipe
“Oju Olorun yio ma ba mi lo ninu irin ajo aye mi gbogbo, beni Oluwa yio si bukun fun mi lopolopo.
Ni Oruko Jesu Kristi. Amin.