Bibeli wipe “Awa si mo pe ohun gbogbo li o nsise po si rere fun awon ti o fe Olorun, ani fun awon eniti a pe gege bi ipinnu re”   

Rom. 8:28

            Mo so pelu igbagbo wipe “Emi yio je iko Kristi nibi gbogbo ti mo ba wa; Nitorina ohun gbogbo yio si se po

fun rere fun mi ati Ebi mi, a ko si ni se alaini ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

 

Leave a Reply