ISOTELE ALAAFIA FUN OSE YI.
Bibeli wipe “Ran owo re lati oke wa, yo mi, ki o si gba mi kuro ninu omi nla, li owo awon omo ajeji” Psalm 144:7
Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun yio na owo Re latokewa, yio si gba mi kuro lowo aponiloju, yio da si oro aye mi ati ebi mi ni Oruko Jesu Kristi. Amin.