ISOTELE  ALAAFIA  FUN  OSE  YI.

Bibeli wipe “Se oju Re ki o mole si iranse Re lara ki o si ko mi ni ilana Re.”

Mo so pelu igbagbo wipe, “Oluwa yoo ko okan mi nipa oro Re, yio si se oju Re mole si Emi ati Ebi mi lara ni Oruko Jesu Kristi. Amin.  Ps. 119:135

Leave a Reply