DECLARATION   OF PEACE FOR THIS WEEK

The Bible says  “… When he ascended up on high, he led captivity Captive, and gave gifts unto men”.  Eph. 4:8

I declare with faith that “The Lord will put whatever wants to put me and my family into captivity captive and bless us with physical and spiritual gifts in Jesus Christ’s Name. Amen.

 

ISOTELE  ALAAFIA  FUN  OSE  YI.

Bibeli wipe “Nigba ti o goke lo si ibi giga, o di igbekun ni igbekun, o si fi ebun fun eniyan”.  Efesu 4:8

Mo so pelu igbagbo wipe, “Oluwa yio di ohunkohun ti o fe di emi ati ebi mi nigbekun, yio si fun wa ni ebun t’ara ati t’Emi

ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

 

Leave a Reply