DECLARATION OF PEACE FOR THIS WEEK
The Bible says “Our God is a God of salvation; and to God, the Lord belongs escape from death”. Ps. 68:20
I declare by faith that I and my household will enjoy the salvation of God, we shall not experience untimely death in Jesus Christ’s Name. Amen.
ISOTELE ALAAFIA FUN OSE YI.
Bibeli wipe “Eniti ise Olorun wa li Olorun igbala; ati lowo JEHOFAH Oluwa li amuwa lowo iku wa. ” Ps. 68:20
Nitori ti Olorun wa je Olorun Igbala, mo so pelu Igbagbo pe iku aitojo ati iku ojiji ko ni je ipin mi ati ebi mi, ni Oruko Jesu Kristi. Amin