ISOTELE  ALAAFIA  FUN  OSE  YI.

Bibeli wipe “Ibukun ni fun okunrin na ti ko rin ni imo awon eniyan buburu, ti ko duro ni ona awon elese, ati ti ko si joko ni ibujoko awon elegan.”

 Niwon igba ti mo ti pinu lati rin ni ona Olorun,

Mo so pelu Igbagbo pe “Mo di alabukun fun ninu Kristi, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

Ps. 1:1

Leave a Reply