ISOTELE  ALAAFIA  FUN  OSE  YI.

Bibeli wipe “Won wo O imole si mo won; Oju ko si ti won.”

 “Niwon igbati mo nwo Olorun fun iranlowo”,  Mo so pelu igbagbo wipe  oju ko ni ti mi lori oro aye mi ati ti ebi mi.   Ni Oruko Jesu Kristi.

Amin  Ps. 34:5

Leave a Reply