ISOTELE ALAAFIA FUN OSE YI
Bibeli wipe “OluwaniOlusoagutanMi, Emi kiyio se alaini.”
“Ni won igbati Jesu ti je Olusoagutan mi”, mo so peluigbagbope, Emiatiebi mi kiyio se alainiohundidarabeniojukiyiotiwanilailai. Ni Oruko Jesu Kristi. Amin.
Ps. 23:1