The Bible says, “Then said Jesus to them again, peace be unto you; as ,my father hath sent Me, even so send I you.”

I declare by faith that the peace of God will be our portion, I and my family will be far from oppression in Jesus Christ’s name.” Amen.

John 20:21

 

ISOTELE ALAFIA FUN OSE YI

Bibeli wipe, “Nitorina Jesu si tun wi fun won pe, Alaafia fun nyin; gege bi Baba ti ran mi, bee ni Emi si ran yin”

Mo so pelu igbagbo wipe, alaafia Olorun yio je I[pin wa, emi ati ebi mi yio jina si inira, ni Oruko Jesus Kristi. Amin. John 20:21

Leave a Reply