The Bible says “Happy is he that hath the God of Jacob for his help, Whose hope is in the Lord his God”.

I declare by faith that God being mine helper, so I and my family will not be put to shame even as the year runs out in Jesus Christ’s Name. Amen.

Ps. 146:5.

ISOTELE  ALAAFIA  FUN  OSE  YI.

Bibeli wipe “Ibukun ni fun eniti o ni Olorun Jakobu fun iranlowo re, ireti eniti nbe lodo Oluwa Olorun re.

“ Nitori pe Oluwa ni Oluranlowo mi, Mo so pelu Igbagbo wipe  oju ko ni timi lori ise ati lori ebi mi  ni iyoku odun yi ati li odun titun. Ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Ps. 146:5.

Leave a Reply